Whaleshares Logo

Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

factismPosted for Everyone to comment on, 5 years ago

Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .

Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.

Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni igi agbon ti ase ra si orí oko wa . Inunwa dun pupo.


![IMG_20190514_122355.jpg]()

Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .

This post was made from https://ulogs.org

Sign Up to join this conversation, or to start a topic of your own.
Your opinion is celebrated and welcomed, not banned or censored!